Letra de ' Olú Ọdẹ ' de Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band

Se você tem procurado há muito tempo pela letra da música Olú Ọdẹ de Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band , comece a aquecer a voz, porque você não vai conseguir parar de cantá-la.

Olu Ọdẹ nde o (ye, nde o)
Olu Ọdẹ nde o (ye, nde o)
Olu Ọdẹ nde o (ye, nde o)
Eemọ wọ'lu o, o ko'ni l'oun lọ
Ijamba ma de o, o n bu rara

Arinka wọ'lu o, o mi pe o ni'ja
Olu Ọdẹ nde o (ye, nde o)
Olu Ọdẹ nde o (ye, nde o)
Olu Ọdẹ nde o (ye, nde o)
Eemọ wọ'lu o, o ko'ni l'oun lọ
Ijamba ma de o, o n bu rara
Arinka wọ'lu o, o mi pe o ni'ja
Oluwa mi, ogirigbamugbamugidigba o ṣe'la
Baba mi, igi agunla ṣedi bẹbẹrẹ s'ọpọn aye
Baba mi, ìmọ́lẹ̀-taanran-bori-ookun-biri
Asape-asala, o-s'opo-d'ọlá, sọ'wọfa d'oyin
Okitiribiti, ko ṣe mì, ko ṣe yi, a-gbe-ni-gun-la
Ina fuuru jo lor'omi, ko-ṣe-dimu, ko-ṣe-fiilẹ
Baba mi, opo-a-lọ-mọ-ye, a-fo-mọ-la
Awo're ti n gb'ọmọ l'ọjọ ewu
Oluwa mi, nde!

Olu Ọdẹ o ma w'ọmọ rẹ o (ko ma w'ọmọ rẹ)
Olu Ọdẹ o ma w'aya rẹ o (ko ma w'aya rẹ)
Olu Ọdẹ o ma w'ẹni rẹ o (ko ma w'ẹni rẹ)
Eemọ wọ'lu o, o ko'ni l'oun lọ
Ijamba ma de o, o n bu rara
Arinka wọ'lu o, o mi pe o ni'ja

Olu Ọdẹ nde o (ye, nde o)
Olu Ọdẹ nde o (ye, nde o)
Olu Ọdẹ o ma w'ọmọ rẹ o (ko ma w'ọmọ rẹ)
Olu Ọdẹ nde o (ye, nde o)
Olu Ọdẹ nde o (ye, nde o)
Olu Ọdẹ o ma w'aya rẹ o (ko ma w'aya rẹ)
Olu Ọdẹ nde o (ye, nde o)

Olu Ọdẹ nde o (ye, nde o)
Olu Ọdẹ o ma w'ẹni rẹ o (ko ma w'ẹni rẹ)
Olu Ọdẹ nde o (ye, nde o)
Olu Ọdẹ nde o (ye, nde o)
Olu Ọdẹ o ma w'ọmọ rẹ o (ko ma w'ọmọ rẹ)
Ye-

Play Escuchar " Olú Ọdẹ " gratis en Amazon Unlimited

Existem muitos motivos para querer conhecer a letra de Olú Ọdẹ de Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band .

Um motivo muito comum para procurar a letra de Olú Ọdẹ é querer conhecê-la bem porque nos faz pensar em uma pessoa ou situação especial.

É importante notar que Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band , nos concertos ao vivo, nem sempre foi ou será fiel à letra da música Olú Ọdẹ ... Então é melhor se concentrar no que a música Olú Ọdẹ diz no disco.

Aprenda as letras das músicas que você gosta, como Olú Ọdẹ de Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band , seja para cantá-las no chuveiro, fazer seus covers, dedicá-las a alguém ou ganhar uma aposta.

Lembre-se que quando precisar saber a letra de uma música, você sempre pode contar conosco, como aconteceu agora com a letra da música Olú Ọdẹ de Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band .